Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ PENGASSAN Fẹ̀hónúhàn, Wọ́n Ti Ọ́ọ́fìsì Pa Ní Ìlú Abuja

0 196

Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ ilé epo rọ̀bì fi ẹ̀hónúhàn, èyí tí ó mú wọn ti ọ́ọ́fìsì pa ní ìlú Abuja látàrí kíkùnà àwọn alákòsóo láti pèsè ohun ìgbáyégbádùn fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ náà

 

Àwọn olùfẹ̀hónúhàn náà tú jáde sí òpópónà lọ́pọ̀ yanturu ní òwúrọ̀ kùtù, tí wọ́n sì dí ojúnà ọ́ọ́fìsì náà, èyí tí ó wà ní àgbègbè Jabi, ní ìlú Abuja

 

Wọ́n ń lùlù, wọ́n sì ń kọrin, wọn ń jó, wọ́n sì kọ̀ láti wọ inú ọ́ọ́fìsì lọ títí tí àwọn alákòsóo yóò fi se ohun ti wọn fẹ.

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button