Ìjọba àpapọ̀ ti pàrọwà sí ẹgbẹ́ òsìṣẹ́ láti sẹ́wélé ìyanṣẹ́lódì tí ó gbèrò àti gùnlé ní Ọjọ́rú láti fẹ̀hónúhàn tako ìgbésẹ̀ ìjọba tí ó wà lóde.
Abẹ́sinkáwọ́ ààrẹ, Fẹmi Gbajabiamila ni ó pàrọwà náà ní ọjọ́ Ìsẹ́gun lẹ́yìn ìpàdé àwọn ìgbìmọ̀ tí ó wà fún ètò ìgbáyégbádùn ará ìlú .
Gbajabiamila salaye pe ifilede ti ààrẹ se ni ọjọ Aje jẹ igbesẹ akọkọ lati mu irọrun ba ara ilu latari yiyọ iranwọ ori epo. Ó tẹ̀síwájú pe ijọba setán láti tẹ́tí sí ìbéèrè ará ìlú, àtipé òun nigbagbọ pe, iyanṣelodi naa koni waye.
Leave a Reply