Take a fresh look at your lifestyle.

Adarí Ilé Akéde Ti Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Pàrọwà Sí Ẹgbẹ́ Òsìṣẹ́ Láti Sẹ́wélé Ìyanṣẹ́lódì

0 182

Ògúnná gbòǹgbò nínú ẹgbẹ́ òsèlú APC, tí ó tún jẹ́ alákòsóo ilé Akéde Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ọ̀gbẹ́ni Osita Okechukwu ti pàrọwà sí adarí ẹgbẹ́ òsìṣẹ́ láti sẹ́wélé ìyanṣẹ́lódì tí wọ́n fẹ́ ẹ́ gùnlé.

 

Okechukwu gbà wọ́n níyànjú láti se àtìlẹyìn fún Ààrẹ Tinubu lójúnà àti mú ìgbòòrò bá ètò ọrọ̀ ajé àti ìgbáyégbádùn ọmọnìyàn.

 

Ó sọ ọ̀rọ̀ náà nígbà ti o n se àgbéyẹ̀wò ìfiléde tí ààrẹ se ní ọjọ́ Ajé. O tẹsiwaju pe, ìrètí wà àtipé ọjọ iwaju yoo dara nitori pe ifilede naa fini lọ́kàn balẹ̀. O wa rọ ẹgbẹ osiṣẹ ati ọmọ Orilẹ-ede lapapọ fun sùúrù àti ìfarajì fun idagbasoke Orilẹ-ede wa.

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button