Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu so pé òun kò se aláìmọ̀ pé nǹkan le koko fún àwọn ọmọ Nàìj́iríà látàrí yíyo ìrànwọ́ orí epo, Ó wá fi ọwọ́ sọ̀yà pé, láìpẹ́ àyípadà rere yóò débá Orílẹ̀-èdè wa.
Ó tún fi àrídájú hàn pé ìgbéga yóò dé bá Orílẹ̀-èdè Naijiria, sugbọn O pàrọwà si ọmọ Naijiria fun ìfaradà kí á le è jẹ ọrọ̀ lẹ́yìn ìlekoko náà.
Ààrẹ fi orọ naa lede nigba ti o sèpàdé pọ̀ pẹ̀lú àwọn gómìnà tẹ́lẹ̀rí ti ọdun 1999 ni ọ́ọ́fìsì Ààrẹ, ni ilu Abuja, níbití ó ti bèrè fún àtìleyìn wọn.
Leave a Reply