Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpín Kejì Àwọn Alálàájì Ìpínlẹ̀ Kwara Gúnlẹ̀ Sí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

0 181

Ọ̀ọ́dúnrún dín díẹ̀ tí ó jẹ́ ìpín kejì àwọn tí ó se ìrìnàjò lọ sí ilẹ̀ mímọ́ láti ìpínlẹ̀ Kwara fún ìjọsìn Hajj ti padà sí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

 

Àwọn arìnrìnàjò náà gbéra ní pápákọ̀ òfurufú Jeddah ni Ọjọ́rú, ọjọ kẹẹ̀wá osù keje, wọn si gúnlẹ̀ sí pápákọ̀ ofurufu agbaye ti o wa ni ìlú Ilọrin ni déédé aago kan abọ ọsan le diẹ.

 

Àfojúsùn wà pé àwọn arinrinajo ti o ku naa ti n bọ lọna. Ajọ NAHCON fi aridaju lede pe gbogbo ètò ti pari lati ri dájú pé gbogbo awọn alalaaji ti o ku pada de láìpẹ́.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button