IKú dóró! Adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin tẹ́lẹ̀rì ,Wayas di olóògbé
Ààrẹ Muhammadu Buhari ti bá ẹbí , ijọba ipinlẹ Cross River, ile igbimọ asofin agba ati ọ̀rẹ́ adari ile igbimọ asofin tẹlẹri oloogbe Joseph Wayas dárò .
Asofin Joseph Wayas jẹ ọmọ ọgọrin ọdun nigba ti o dagbere fáyé pe o…