Ìkọlù Àwọn ọlọ̀tẹ̀: Nàìjíríà, UK Ṣèlérí Ìdájọ́ òdodo Fún Gbogbogbòò
Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí àti ọ̀gá àgbà Mínísítà Boris Johnson, ti Ìlú Gẹ̀ẹ́sì ní ọjọ́bọ̀, ṣe àtúnyẹ̀wò ìgbógunti àwọn oríṣiríṣi ìwà jàgídíjàgan ní Nàìjíríà, àti pé ó tún gbà pé wọ́n ní láti…