Iná Mọ́nà-mọ́na: Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ Buwọ́lù €3.7 Mílíọ̀nù
Àwọn ìgbìmọ̀ aláṣẹ tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní Ọjọ́rú fọwọ́sí ìyé owó tí ó tó mílíọ̀nù mẹ́ta-lé-méjé Euro €3.7 bi iyé owó àdéhùn fún Ilé-iṣẹ́ tó ń pèsè ìnà mọnamọna (Transition company of Nigeria) látí rá àwọn òun èlò látí túbọ parí iṣẹ́…