Senegal Gbá Ìfé U-20 AFCON Lọ́wọ́ Gambia Nínú Ìdíje TotalEnergies
Àwọn ọdọ Teranga Lions tí Senegal lú aladugbo rẹ̀ Gambia ní ọjọ́ Àbámẹ́ta látí gbà ìfé TotalEnergies U-20 Africa Cup of Nations.
Àmì ayò látí ẹ̀sẹ Sulaymane Faye àtí Mamadou Camara ní Olú-ìlú Egypt ní Cairo ló mú Senegal bórí…