Akọrin Nàìjíríà, Tems kọrin pẹ̀lú Future nínú àwo tuntun rẹ̀ tó jáde
Èwe Olórin Nàìjíríà kan,tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Tems ti kọrin nínú àwo orin tuntun tí ó tún jẹ́ ẹlẹẹ̀kẹsàn akọrin Amẹ́ríkà, Future, tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ ‘I Never Liked You’,
Awo-orin naa ti o ni akọle mẹrindinlogun ni Tems ati ọmọ ilu…