Sunday Igboho gba ìtúsílẹ̀ lọ́gbà ẹ̀wọ̀n Benin Republic
Aṣiwaju ,a-ji-ja-gbara fun idasilẹ orilẹ ede Yoruba, Oloye Sunday Adeyẹmọ , ti a mọ si ,Sunday Igboho ni awọn alaṣẹ orilẹ ede Benin Republic ti fi silẹ ninu ahamọ ti wọn fi si.
Iroyin sọ pe ijọba orilẹ ede Benin fi Ajijagbara ọhun silẹ…