Japan, South yóò pawọ́pọ̀ láti Kojú ìpeniníjà ààbò agbègbè
Àwọn adarí orílẹ̀-èdè Japan àti South Korea ti pinnu láti ṣiṣẹ́ papọ̀ fún ìkojú ìpeniníjà ààbò agbègbè.
Àwọn adarí méjèèjì pinnu láti fòpin sí ìkóríra ààrin wọn níbi àpèjọ kan, ní Ọjọ́bọ̀,láàrin…