Ìpèníjà lórí ètò ààbò kò ní pẹ́ dópin-Osinbajo
Igbakeji aarẹ orilẹ ede Naijiria, ojọgbọn Yemi Osinbajo ti ni awọn ipenija ti orilẹ ede Naijria ń dojukọ ko ni pe di ohun igbagbe laipé.
Osinbajo,sọrọ yii lọjọBọ lasiko to n tẹwọgba awọn ẹgbẹ alatilẹyin fun aarẹ Muhammadu Buhari , iyẹn…