Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Tag

Òsínbàjò ń darí àpèjọ ìgbìmọ̀ aláṣẹ

Igbákejì ààrẹ, Òsínbàjò ń darí ìgbìmọ̀ ìjọba àpapọ̀

Igbákejì ààrẹ orílẹ̀-èdè,ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọ̀sínbàjò ń darí  ìgbìmọ̀ ijọba apapọ aláṣẹ lórí ayélujára,èyí tí ó bẹ̀rẹ̀ ní agogo mẹ́wàá òwúrọ̀ ní ọjọ́ọ́rú. O jẹ ipade igbimọ  akọkọ lati igba ti aarẹ Muhammadu…