Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yóò túnbọ̀ tẹra mọ́ ìdókòwò wọn pẹ̀lú orílẹ̀-èdè Bẹ́ljíọ́mù
Aṣojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sí Bẹ́ljíọ́mù, Obinna Onowu, ti ṣèlérí láti jẹ́ kí àjọṣepọ̀ ọrọ̀-ajé jinlẹ̀ láàrin Nàìjíríà àti Bẹ́ljíọ́mù jákèjádò gbogbo àwọn ẹ̀ka.
Ọgbẹni Onowu sọ eyi lakoko ti o n fi awọn…