Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Gáḿbíà fìmọ̀ ṣọ̀kan láti kojú àwọn ọlọ̀tẹ̀.
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Gáḿbíà ti buwọ́ lu ìwé àdéhùn lórí ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn ọmọ ogun láti kojúu àwọn ọ̀daràn tó ń da orílẹ̀ èdè wọn láàmú.
Oludamọran pataki si Minisita fun Aabo, Mohammed Abdulkadri,…