Olu-ilu: Ọwọ́ pálába àwọn afurasí ségi
Ọwọ́ Ilé-iṣẹ́ tó ń mójútó ètò olú-ìlú,FCTA,ti tẹ Àwọn Afurasí márùn ún kan tí wọ́n ń tà àti lo òògùn olóró Lábẹ́ afárá ní Wusé,ní ìlú Àbújá.
Igbesẹ yii jẹ apakan eto lati palẹmọ awọn ile ti ko bofin mu…