Ìjọba Nàíjíríà, ẹ lo owó tí ẹ bá yá fún ìdàgbàsókè ètò okoòwò – Peter Obi
Gomina ìpínlẹ̀ Anambra tẹ́lẹ̀rih , Peter Obi, ti rọ ìjọba orílẹ̀ èdè Nàíjíríà láti máa lo owó tí wọ́n bá yá fún ìdàgbàsókè ètò okoòwò lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà.
Obi, tẹsiwaju pe, kii se nnkan buruku ni ki…