Nàìjíríà Àtí Íńdíà Ṣe Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Lórí Ìwádìí Ìmọ-jinlẹ̀ Ojú-ọjọ́ Àtí Ìdàgbàsókè
Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti ìjọba orílẹ̀-èdè India tí fọwọ́ sí ìwé àdéhùn (MoU) fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ lórí iṣẹ́ ìmọ-jinlẹ̀ ojú-ọjọ́, ìwádìí ìmọ-ẹrọ àtí ìdàgbàsókè.
Àdéhùn náà ní a fọwọ́ sí ní orúkọ Ilé-iṣẹ́ Oju-ọjọ Nàìjíríà (NiMet)…