NEMA pín àwọn oun èlò ìtura fún àwọn olùfaragbà omíyalé ní ìpínlẹ̀ Kánò
Ilé iṣẹ́ tó ń rísí ìṣàkóso pàjáwìrì lórílẹ̀-èdè (NEMA), pẹ́lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ilé-iṣẹ́ tó ń rísí ìṣákóso pájáwìrí ní ìpínlẹ̀ Kánò (SEMA), ti pín àwọn ohun èlò ìtura fún àwọn olùfaragbà ìjàǹbá…