Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Tag

Nàìjíríà

Nàìjíríà, Bulgaria yóò túnbọ̀ fìdí ètò ẹ̀kọ́ ààrin wọn múlẹ̀ si

Mínísítà fún ètò Ẹ̀kọ́, Ọ̀jọ̀gbọ́n Tahir Mamman, ti sọ pé Nàìjíríà ti ṣetán láti túnbọ̀ fìdí àjọṣepọ̀ pẹ̀lú orílẹ̀-èdè Bulgaria múlẹ̀ ní abala ètò ẹ̀kọ́. Minisita naa wa pinnu pe wọn yoo ṣe eto isọdọtun adehun…

Nàìjíríà, Gambia yóò túnbọ̀ fọwọ́sowọ́pọ̀ lórí ètò ìmọ̀ ẹ̀rọ ìbáraẹnisọ̀rọ̀

Nàìjíríà àti Gambia yóò túnbọ̀ tẹ̀sìwájú lórí àjọ̀ṣepọ̀ wọn lórí ìdàgbàsókè ètò ìmọ̀ ẹ̀rọ ìbáraẹnisọ̀rọ̀, (ICT). Alákòóso olùdarí Broad Service Privider,Galaxy Backbone, ní Nàìjíríà,ọ̀jọ̀gbọ́n…

Nàìjíríà, Àwùjọ Àgbáyé, Àwọn mìíràn fọwọ́ sí i láti fòpin sí ìdábẹ́ ọmọbìnrin FGM

Ìjọba Nàìjíríà, àwùjọ àgbáyé, àwọn olùkópa pàtàkì àti àwọn àjọ tí kìí ṣe tìjọba ti pinnu láti fòpin sí Ìdábẹ́ fún ọmọbìnrin ní Nàìjíríà. Wọn ṣe ipinnu naa nibi “Ifilọlẹ  igbesẹ lati fopin si abẹ dida fun ọmọbinrin” ni ilu Abuja.…

Nàìjíríà, Kòríà yóò bẹ̀rẹ̀ ìpele Kejì Ìjọba nípa lílo ìmọ̀ ẹ̀rọ

Lẹ́hìn  tí ìpele àkọ́kọ́  iṣẹ́ àkànṣe ìjọba lílo ìmọ̀ ẹ̀rọ ti jẹ́ àṣeyọrí, Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti  Kòríà ti ṣètò láti bẹ̀rẹ̀ ìpele kejì  iṣẹ́ àkànṣe ní Nàìjíríà. Minisita fun Ibaraẹnisọrọ ati…
button