Ààrẹ Buhari dárò ikú asòfin ìpínlẹ̀ Zamfara
Aarẹ orilẹ ede Naijiria, Muhammadu Buhari ti daro iku asoifn ipinlẹ Zamfara, Muhammad Ahmad .
Awọn agbebọn pa Ahmad loju ọna Kano sí Shema/Funtua .
Ninu iwe ti aarẹ kọjade lati fi sedaro iku asofin ọhun, aarẹ ni: “Inu mi bajẹ…