Mozambique Bẹ̀rẹ̀ Àtúnṣe Àgbègbè Kàn Lẹyìn Ìjì Líle Cyclone
Ààrẹ Mozambique, Filipe Nyusi tí kéde ìpínu rẹ̀ látí pín mílíọ̀nù mẹ́ta lé díẹ̀ fún àtúnkọ àwọn ilé-ìwé, ilé ìgbé àtí àwọn òun amàyédẹ́rùn mìíràn bótílẹ̀jẹ́pé owó náà kere púpọ̀.
Ìjì líle náà ṣẹ̀lẹ̀ ní òpin ọ̀sẹ̀ tó kọjá, ẹ́lẹ̀ẹ́kéji…