Mítà iná mọ̀nàmọ́ná mílíọ́nù mẹ́fà lóti wà nílẹ̀ fún àwọn ará ìlú báyìí
Olùdárí Alákóso, Ilé-iṣẹ́ tó ń ṣàkóso iná mọ̀nàmọ́ná ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, NEMSA àti ọ̀ga àgbà Olùyẹ̀wò iná mọ̀nàmọ́ná lápapọ̀, Peter Ewesor sọ pé, Ìjọba ti gbèrò láti gbé àwọn mítà iná…