Mbappe Dì Balógun Ìkọ France Lẹyìn Ìfẹyìntì Hugo Lloris
Kylian Mbappe dì balógun ìkọ àgbábọ́ọ̀lù Faransé lẹyìn tí balógun tẹlẹ rí Hugo Lloris kéde ìfẹyìntì, àwọn òníròyìn to súnmọ́ ẹgbẹ́ náà sọ.
Àgbábọ́ọ̀lù ọwọ́ iwájú fún Paris Saint-Germain PSG Mbappe, 24, gbà lẹyìn àwọn ìjíròrò pẹ̀lú…