Ilé Aṣòfin Eko dábàá ṣíṣe ìdásílẹ̀ ilé ẹ̀kọ́ fáfitì méjì
Ile Igbimọ Aṣofin Ipinlẹ Eko ti jiroro lori abadofin meji ti yoo ṣe idasilẹ ile ẹkọ giga meji ni ipinlẹ yii. Eyi ni Ifafiti Imọ eto Ekọ ati Ifafiti fun Imọ-ẹrọ.
Awọn abadofin mejeeji ti wọn gba wọle ni igba keji ninu…