Ilé Aṣòfin Èkó rọ ìjọba láti tètè dènà ìtànkálẹ̀ ìpéle kẹta àrùn COVID-19
Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣ̀ofin Ìpínlẹ̀ Èkó ti rọ ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀-èdè Nàíjíríà àti ijọba Ipinlẹ Eko lati mojuto àwọn arìnrìn-àjò tó ń wọ orílẹ̀-èdè yìí láti le dènà ìtànkálẹ̀ ìpele kẹta àrùn…