Àwọn ọmọ ilé -ìwé Islamiyya tí àwọn ajínigbé kó lọ ti gba òmìnira
Àwọn ọmọ ilé -ìwé Islamiyya tí àwọn ajínigbé kó lọ ni ìpínlẹ̀ Niger ti gba òmìnira ni àsálẹ́ ọjọ́Bọ̀.
oludari ile-iwe ọhun , Alhassan Abubakar lo fidi ọ̀rọ̀ naa mulẹ lasiko ifọrọwerọ pẹlu akọroyin ile akede Naijiria, Voice…