Ààrẹ Buhari ti padà sí ìlú Abuja láti Daura, ní ìpínlẹ̀ Katsina
Aarẹ orilẹ ede Naijiria, Muhammadu Buhari ti pada si ilu Abuja, to jẹ olu ilu orilẹ ede Naijiria lẹyin ọjọ mẹjọ ti o lo ni ipinlẹ re iyẹn ipinlẹ Katsina , nibi ti o ti lọ ba wọn se ayẹyẹ ọdun Eid al-Adha ni ilu rẹ to wa ni Daura.
Aarẹ…