Rògbòdìyàn Russia-Ukraine Ní Yóò Kópa Nlá Níbí Ìpàdé G20
Rògbòdìyàn láàárín Russia àtí Ukraine ní yóò jẹ́ apakan pàtàkì tí wọ́n yóò jíròrò lè lórí níbí ìpàdé àwọn Mínísítà ilẹ̀ òkèèrè G20, ṣùgbọ́n India tó jẹ́ olugbalejo ṣé ìdánilójú náà látí ẹnu Mínísítà ilẹ̀ òkèèrè Vinay Kwatra pé, àwọn…