Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Tag

Ilé-iṣẹ́ tí ó ń tẹ owó ní orílẹ́-èdè Nàìjíríà gbegedé lórí títẹ owó jáde

Ilé-iṣẹ́ tí ó ń tẹ owó ní orílẹ́-èdè Nàìjíríà fi gbegedé sórí títẹ owó jáde

Olùdarí Alákóso, ilé-iṣẹ́ ìtẹwó ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, NSPMC, Abbas Umar Masanawa sọ pé, ilé-iṣẹ́ ọ̀hún ti ṣàṣeyọrí tó lámì nínú títẹ  owó síta ní orílẹ̀-èdè Naijiria. Ile-iṣẹ naa tun ni agbara  lati tẹ…