Ẹgbẹ́ ọmọ ogun Bẹ́rẹ̀ẹ̀ ìpele Kejì, ìkẹta Àpèjọ COAS Lónìí
Ọ̀gá àgbà fún àwọn ọmọ -ogun ti bẹ̀rẹ̀ àpapọ̀ Àpèjọ ìpele Kejì àti Kẹta tí ọdún 2021, ní Ìlú Àbújá ní ọjọ́ kẹtàlá,ọjọ́ àìkú, Oṣù Kẹsàn- án,ọdún 2021.
Apejọ COAS yii n waye ni ibujoko Ile – igbalejo ti o wa…