Igbákejì ààrẹ: A kò ní fi ààyè gba ìwà ìfipá múni
Igbákejì ààrẹ Yemí Òsìńbàjò ti tẹnumọ́ akitiyan Ìjọba àpapọ̀ pé, òhun kò ní fi ààye gba ìwà ìfipá mú ènìyàn (GBV) tí ó sì tún mu dájú pé ,irú ẹni tí wọ́n bá fi ìyà náà jẹ yóò rí eto ààbò àti…