Guardiola Sọ pé Haaland yóò rí ẹ̀kọ́ kọ́ nípa ìkọ́ṣe Harry Kane
Alákóso Manchester City , Pep Guardiola sọ pé agbábọ́ọ́lù, Erling Haaland yóò rí ìlọsíwájú tí ó bá ń wò àti kọ́ṣe láti ara ẹnìkejì rẹ̀ ti Tottenham Hotspur ,Harry Kane, ní ìgbáradì fún ìfigagbága Premier…