Gómìnà Násáráwá ti ní kí ìgbìmọ̀ ìjọba rẹ̀ lọ rọ́kún sílẹ́
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Násáráwá, Abdullahi Súlè ti tú Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ Ìpínlẹ̀ náà ká.
Gomina ipinlẹ naa ni o ṣe ikede ituka naa nibi ipari ipade awọn alaṣẹ pẹlu Awọn oludamọran Pataki, ati Awọn Oluranlọwọ Pataki Agba. Otun…