FEC: Ḿinísítà fún Àwọn ọ̀dọ́ yóò Ṣàgbékalẹ̀ Àtẹ̀jáde NYSC kan lórí Owó Ìrànlọ́wọ́
Mínísítà fún Àwọn ọ̀dọ̀ àti Ìdàgbàsókè Eré-ìdárayá ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Sunday Dare, ti ṣe ìlérí láti ṣàgbékalẹ̀ ìwé-ákọọ́lẹ̀ fún ìdásílẹ̀ owó ìrànlọ́wọ́ fún àgùnbánirọ̀ (NYSC) fún …