Ewu: Pàtàkì ipa obìnrin láti mú àláfíà jọba láyíká wọn
Àjọ tó ńrísí ìbáṣepọ̀ gbogbo àgbáyé UN ti sọ pé ,óṣe pàtàkì púpọ̀ láti gba àwọn obìnrin láyè lórí ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti ìfọ̀rọ̀wérọ̀.
Ajo Agbaye (UN), ti pe fun ifisi ni kikun ati ikopa awọn obirin ninu…