Ẹgbẹ́ ọmọ ogun sún sí ìpínlẹ̀ Rivers fún ìgbaniwọlé síṣẹ́
Ẹgbẹ́ ọmọ ogun ti rọ àwọn ènìyàn Ìpínlẹ̀ Rivers, gúsù Nàìjíríà láti kópa nínú ìgbanisíṣẹ́ lọ́pọ̀ yanturu sí 84 Rular Recruit Intake,RRI,tí ó ń lọ Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí.
Olùdarí,ètò òṣìṣẹ́ ti Ẹ̀ka ìṣàkóso…