Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Tag

EFCC

Gómìná Ìpínlẹ̀ Kogi Tẹ́lẹ̀ Rí Ti Di Ẹni Tí Ìjọbá Ń Wá Látàrí Ẹ̀sùn Kíkó Owó Ìlú…

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà ti fi Gómìná Ìpínlẹ̀ Kogi Tẹ́lẹ̀ Rí, Yahaya Bello si ori patako eni ti wọn n wa, wọn si ti fi to àwọn ologun Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà àti awọn àjọ to n mójútó ìrìnà létí láti gbe ní…

EFCC, ẹ̀sọ́ ibodè pinnu láti kojú wíwa ìtura ilẹ̀ lọ́nà àìtọ́ ní ìpínlẹ̀ Ọyọ àti Ọṣun

Igbimọ to n mojuto ọran ọrọ aje ati inawo, ikọ  Ibadan, EFCC, ati ile iṣẹ ẹ̀sọ́ ibodè Naijiria ikọ agbegbe ipinlẹ Ọyo, NCS,ti pinnu lati fọwọsowọpọ fun igbogunti wíwa ìtura ilẹ̀ lọ́nà àìtọ́ ní ìpínlẹ̀ naa. Awọn ile iṣẹ naa ṣe…
button