COVID-19: Ẹ̀yin ẹgbẹ́ òsèlú , ẹ́ máa tẹ̀lé ìlànà gbígbógun ti àrùn Corona
Ìgbìmọ̀ ijọba apapọ to n mojuto gbigbogun ti arun COVID-19 lorilẹ ede Naijria ti sèkìlọ̀ fun gbogbo ẹgbẹ oselu to wa lorilẹ ede Naijria lati maa tẹlẹ ilana aarun Corona.
Igbimọ sekilọ yii nitori bi arun COVID -19 se n pọ si lorilẹ…