COVID-19: Nàíjíríà yóò tún bẹ̀rẹ̀ ìpéle gbígba abẹ́rẹ́ àjẹsára Corona míràn
Ìjọba orílẹ̀ èdè Nàíjíríà ti ní àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà kò ní pẹ́ bẹ̀rẹ̀ si ní máa gba abẹ́rẹ́ àjẹsára COVID-19.
Minisita fún ètò ìlera, lorilẹ ede Naijiria, Osagie Ehanire lo kede eyi niluu …