COVID-19: Àwọn ènìyàn mẹ́tàdínláàdọ́ta míràn tún ti ní àrùn korona
Ajọ to n mojuto ajakalẹ arun lorilẹ ede Naijria tun ti kede pe awọn eniyan mẹ́tàdínláàdọ́ta miran tun ti ni arun COVID-19.
Ajọ NCDC lo kede eyi lori itakun ẹrọ Facebook wọn lọjo Ẹti pe awọn ipinlẹ ti arun ọhun ti jẹyọ ni “Plateau-…