COVID-19: Àwọn ènìyàn márùndínaláàdọ́ta míràn tún ti ní Corona
Àwọn ènìyàn márùndínaláàdọ́ta (45) míràn tún ti ní arun COVID-19 ti a mọ si COVID-19.
Ajọ to n mojutọ ajakalẹ arun lorilẹ ede Naijiria lo kede rẹ lori ẹrọ ayelujara lọjọ Abamẹta.
NCDC tẹsiwaju pé ipinlẹ mẹfa ni awọn…