Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Flying Eagles kọrin ìyà sí ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Argentina létí pẹ̀lú àmì ayò méjì sí…
Ẹgbẹ́ Agbábọ̀ọ̀lù Nàíjíríà U-20 tí a mọ̀ sí Flying Eagles ṣe bẹbẹ ni ọjọ́ kọkànlẹ́lọ́gbọ̀n, oṣu karùn-ún, ọdun 2023, ọjọ́ tó gbẹ̀yìn ninu oṣù karùn-ún
Wọ́n lu Ikọ̀ Ẹgbẹ́ Agbábọ̀ọ̀lù Argentina ní àmì ayò méjì sódo, Ẹgbẹ́ Agbábọ̀ọ̀lù…