Ìjọba orílẹ̀ èdè Nàíjíríà bẹ̀rẹ̀ oúnjẹ ọ̀fẹ́ ní ìpínlẹ̀ Borno
Àjọ tó ń mójútó ètò ọmọnìyàn, àjálù àti ìdàgbàsókè àwùjọ pẹ̀lú àjọs̀epọ̀ ìjoba ìpínlẹ̀ Borno ti bẹ̀rẹ̀ láti máa fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ní oúnjẹ ọ̀fẹ́.
.Eto ounje ọfẹ yii waye lati…