Ẹ pa gbogbo àwọn ọ̀daràn pátápátá run lórílẹ̀ ède Naijiria-Aarẹ Buhari
Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà , Muhammadu Buhari ti korò ojú sí bí àwọn ọ̀daràn se ń pa àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà, bí eku pàápàá jùlọ ní àwọn ìpínlẹ̀ Zamfara àti Kaduna
Aarẹ Buhari wa tun rọ awọn…