Ẹ jẹ́ asojú rere lórílẹ́ èdè Nàíjíríà àti ní Afirika lójúnà ìrìn -àjò yín lọ sí…
Ọgagun Udounwa ti rọ awọn jẹ aṣoju ikọ ọmọ ogun orilẹ ede Naijiria lati jẹ asoju rere orilẹ -ede Naijiria, lakoko irin -ajo wọn lati ni ẹkọ̀ to ye kooro nipa imọ agbegbe ati lori eto aabo ilu.
Irin -ajo ti o bẹrẹ ni ọjọ…