Àwọn ológun fipá gbàjọba ní orílẹ̀-èdè Guinea
Ìjọba orílẹ -èdè Nàìjíríà bẹnu àtẹ́ lu ìfipá gbàbjọba tó wáyé ní orílẹ̀-èdè Guinea Ní ọjọ́ kẹfà, Oṣù Kẹsàn án, ọdún 2021, ó ṣe àpèjúwe rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi “ó jẹ́ ìfọwọ́ pòfin Ìlànà àjọ tó ń mójútó…