Àwọn ìyàwó àwọn gómìnà Àriwá gbógun ti ìwà ìṣègbèfábo-akọ àti lílo òògùn…
Àpèjọ Àwọn ìyàwó gómìnà Àriwá, N-GWF sọ pé àfọkàn sùn òhun fún ọdún 2021-2022, ni láti kojú ìṣègbèfábo-akọ àti lílo òògùn olóró ní agbègbè Áriwá.
Ninu awọn asọye rẹ, Alaga Apejọ Awọn iyawo gomina…