WTT: Quadri Ṣẹ́gun Alexis Látí Dé Ìpele Ẹlẹ́ni-Mérìndínlógún
Gbajugbaja àgbábọ́ọ̀lù ẹlẹ́yìn lórí tábìlì tí Nàìjíríà, Quadri Aruna, Ṣẹ́gun Alexis Lebrun ọmọ orílẹ̀-èdè France, ní àmì ayò 3-2 nínú ìdíje àgbáyé "World Table Tennis Championship 2023" tí àwọn Ọkùnrin tó ń lọ́ lọ́wọ́ bí ó ṣé yégé sí ìpele…